Back to: Yoruba Primary 2
(formation of one- tone words with one syllable)
- L + ù = lù
- P + ọ̀ = pọ̀
- S + àn = san
- G + ùn = gùn
- K + o = kọ̀
- P + ọ̀n = pọ̀n
- W + à = wà
- P + è = pè
- Gb + à = gbà
- J + ò = jò
IṢẸ́ ṢÍṢE
Ṣèdá ọ̀rọ̀ onísílébù kan tó jẹ́ olóhùn ìsàlẹ́.
- T + ọ̀ =
- F+ ẹ̀ =
- G+ ùn =
- T + à =
- B+ ù =
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]