ṢÍSẸ̀DÁ Ọ̀RỌ̀ ONÍSÍLÉBÙ MÉJÌ OLÓHÙN ÌSÀLẸ̀ (DÒ)  (formation of low- tone words with two syllables)

(FORMATION OF LOW- TONE WORDS WITH TWO SYLLABLES)

  1. Ì + lù = ìlù
  2. Ẹ̀ + wà = ẹ̀wà
  3. Ẹ̀ + gbà = ẹ̀gbà
  4. Ẹ̀ + wù = ẹ̀wù
  5. Ì + gbà = ìgbà
  6. À + gbà = àgbà

ISE SISE

ṢẸ̀DÁ Ọ̀RỌ̀ ONÍSÍLÉBÙ MÉJÌ TÓ JẸ́ OĹOHÙN ÌSÀLẸ̀

  1. Ọ̀ + rọ̀ =
  2. Ẹ̀ + yọ̀ =
  3. Ẹ̀ + gbà =
  4. Ì + sọ̀ =
  5. Ẹ̣̀ + t àn =
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!