ÀṢÀ IRUN DÍDÍ (weaving)

Ní àwújọ awọn Yorùbá, àwọn obìnrin ni dirun. Kò sí àrà tí wọn kò lè fi irun orí wọn dá ní àtijọ́. Díẹ̀ lára irúfẹ́ irun tí àwọn ìyá wa máa ń du ní àtijọ́ ni: kòlẹ́sẹ̀, ṣùkú, òjò-ń-petí, ìpákọ̀- ẹlédẹ̀, kọ̣júsọ́kọ, kẹ̀yìnsórogún, panumọ́, olówu-dúdú, korobá, pàtẹ́wọ́ ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Ní òde òní, àwọn irun tí à ń dì ní: Ṣadé Adú, all back and base, two steps, binta my daughter, Police cap, Evelyn King, pàtẹ́wọ́ at bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Iṣẹ́ òòjọ́ ni iṣẹ́ irun dídì jẹ́ ní àárin àwọn Yorùbá.

 

“Ojú gbooro” ni à ń kí onídìrí, òun náà á sì dáhùn pé, “òòyá á yà”

 

IṢẸ́ ṢIṢE

  1. Kọ orúkọ oríṣii irun márùn-ún tí wọ́n ń dì ní ayé àtijọ́
  2. Kọ orúkọ oríṣìí irun márùn-ún tí wọ́n ń dì ni òde- òni.
How Can We Make ClassNotesNG Better? - CLICK to Tell Us Now!

Pass WAEC, JAMB, NECO, BECE In One Sitting CLICK HERE!

Watch FREE Video Lessons for Best Grades on Afrilearn HERE!💃

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!