ERÉ ÌDÁRAYÁ (games)

Eré ìdárayá pọ̀ jaburata láàrin àwọn Yorùbá. Nígbà tí ọ̣wọ́ bá dílẹ̀ pàápàá jùlọ ní alẹ́ nígbà tí oṣùpá bá yọ ni wọ́n máa ń ṣe àwón éré wọ̀nyí. Ànfàání wà nínú eré ìdárayá tí àwọn ọmọdé wọ̀nyí ń ṣe bí wọ́n bá lè tẹra mọ́ ọn. Bi ọmodé bá ṣe eré ìdárayá yóò làágùn, gbogbo ọmi to lè fa àìsàn tó wà nínú ara rẹ̀ yóò sun jáde. Eré ìdárayá àwọn ọmọdé nìwọ̀nyi:

Bojúbojú
Tenten
Ẹyẹ mẹ́ta tolongo wáyé
Ta ló wà nínú Ọgbà náà
Òkìtì títa
Ayò títa.

IṢẸ́ ṢÍṢE

Dárúkọ eré ìdárayá Yorùbá méje tí o mọ̀. List 7 yoruba games that you know)

 

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!