ORÚKỌ́ ÀWỌN ẸRANKO ( names of different animals)

Ẹran Ilé ( Domestic Animals)

Ajá (dog)
Ewúrẹ́ (Goat)
Àgùtàn (sheep)
Adìyẹ ( fowl)
Tòlótòló ( turkey)
Ehoro (rabbit)
Ìgbín (snail)
olóńgbo (cat)

Ẹran  Igbó ( Wild Animals)

Kìnìún (lion)
Ọ̀nì (crocodile)
Àmọ̀tẹ́kùn ( leopard)
Ìkookò (wolf)
Ẹkùn (tiger)
Ejò ( snake)
Erin (elephant)

IṢẸ́ ṢIṢE

Dárúkọ́ àwọn ẹranko ilé àti éranko igbó marùn- marùn

Ẹranko ilé Ẹranko igbó
   
   
   
   
   
How Can We Make ClassNotesNG Better? - CLICK to Tell Us Now!

Pass WAEC, JAMB, NECO, BECE In One Sitting CLICK HERE!

Watch FREE Video Lessons for Best Grades on Afrilearn HERE!💃

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!