Back to: Yoruba Primary 2
Tití ń ṣe àìsàn
Ó lọ sí ilé ìwòsàn
Dọ́kítà kọ́ oògùn àti abẹ́rẹ́ fún un.
Títí rà wọ́n
Ó lo oògun náà
Ó gba abẹ́rẹ́ pẹ̀lú
Ara Tị́tị́ ti yá báyìí.
IṢẸ́ ŚIŚE
Ka àwọn gbólóhùn Yorùbá òkè wọ̀nyi kí o sì tún wọn ko.( read the Yoruba sentences and re-write them)
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session nowGet more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]