Back to: Yoruba Primary 2
Ìmọ́tótó dára, kìí àrún àti àìsàn lè wọlé sí wa lára. Kò dára kí ènìyàn ya ọ̀bùn rárá, ìwà ọ̀bùn lè ṣe àkóbá fún àgọ́ ara wa. Àwòrán ìsàlẹ̀ wọ̀nyí ń ṣe àfihàn àwọn ìwà ìmọ́tótó tó yẹ kí á máa wú nígbà gbogbo.






Pass WAEC, JAMB, NECO, BECE In One Sitting CLICK HERE!