Ọ̀RỌ̀- ORÚKỌ ( Noun)

Ọ̀rọ̀ – orúkọ ni orúko èniyàn, ẹranko, ibìkan àti nǹkan.

Orúkọ ẹranko: Ajá, ewúrẹ́, adìyẹ, ọ̀pọ̀lọ́, ẹyẹ, ejò, erin, ìjàpá, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Orúkọ Ibìkan: Ìkọtún, Ẹgbẹ́́dá, Amẹ́rikà, Ìlọrin,. ọjà, at bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ

Orúkọ Nǹkan: àga, igi, bọ́ọ̀lu, ìwé, irun, Aṣọ, ife, garawa àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ

 

IṢẸ́ ṢIṢE

Dárúkọ mẹ́ta- mẹ́ta tó bá ìsọ̀rí wọ̀nyí mu:

  1. Orúkọ ẹranko:
  2. Orúkọ ibìkan:
  3. Orúkọ ènìyàn:
  4. Orúkọ Nǹkan
Your Opinion Matters! Quickly tell us how to improve your Learning Experience HERE

Pass WAEC, JAMB, NECO, BECE In One Sitting CLICK HERE!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!