Back to: Yoruba Primary 2
Nínú ìwé alákọ̀ọ́bẹrẹ̀ kìn-ín-ní, a ti ko ekọ́ òǹkà Yorúba láti ori oókan dé orí ogún. Ní ìpele kejì yìí, ẹ̀kọ́ ò̀ǹkà wa yóò tẹ̀síwájú láti orí oókànlélógún dé orí àádọ́ta.
Ìròpọ̀ (+) ni a ó máa ṣe tí a ó fì dé orí ẹẹ́rinlélógún.
20 + 1 = 21 oókànlélógún
20 + 2 = 22 eéjìlélógún
20 + 3 = 23 ẹẹtàlélógún
20 + 4 = 24 ẹẹ́rìnlélógún
Ìyọkúrò (-) àṣewásẹ́yìn ni a ó máa ṣe tí a ó fi dé ori oókandínlọ́gbọ̀n.
30 -5 = 25 aárùn-úndínlọ́gbọ̀n
30- 4 = 26 ẹẹ́rìndínlọ́gbọ̀n
30 -3 = 17 eetadinlogbon
30 -1 = 29 oókàndínlọ́gbọ̀n
30 = 30 ọgbọ̀n.
Ìròpọ̀ (+) ni a ó máa ṣe tí a ó fì dé orí ẹẹ́rinlèlọ́gbòn
30 + 1 = 31 oókànlélọ́gbò́n
30 + 2 = 32 eéjilélọ̀gbọ̀n
30 + 3 = 33 ẹẹ́tàlẹ́lọ́gbòn
30 + 4 = 34 ẹeṛ́inlélọ́gbòn abbl
35- aárun-úndinlógóji
36- ẹẹ́rìndínlógójì
37- ẹẹ́tàdinlógójì
38 oókàdínlógójì
40 – ogójì
41- Oókànlélógójì
42- eéjilélógójì
43- ẹẹ́talélógójì
44- ẹẹ́rìnlélógójì
45- aárùn-úndínláàdọ́ta
46- ẹẹ́rìndínláàadọ́ta
47- ẹẹ́tàdínláàádóta
48- eéjìdínláàádọ́ta
49- oókàndínláàádọ́ta
50- àádọ́ta.
ÌṢẸ́ ṢÍṢÉ
Kọ àwọn fìgọ̀ wọ̀nýi ni èdè Yorùbá: (write the following figures in Yoruba language)
29=
22=
40=
33=
27=
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session nowGet more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]