Back to: Yoruba Primary 1
Gbọgbo àsìkò tó wà ńinú ọ̣dún ni ìkínI wà fún ni àwujọ Yorùba. Ọ̀kan pàtàki lára àwọn ọ̀na tí à ń gbà láti mọ ọmọlúàbi ni ikíni jẹ́. Ni ilẹ̀ Yorùba, ọkùnrin a máa dọ̀bál̀ẹ̣̀ nígbá tí obìnrin á fi orúnkún rẹ̀ méjéèjì kúnlẹ̀ láti kí àgbàlagbà.
Ọ̀rọ̀ tó yẹ láti mọ̀
Ààro – morning
Ìrọ̀lẹ́ – evening
Ọ̀sán – afternoon
Kúnlẹ̀ – kneel down
Ọkùnrin – male
Obìnrin – female
Dọ̀bálẹ̀ – postrate
Àgbàlagbà – elder
IṢẸ́ ṢÍṢE
Dáhùn ìbéèrè wọ̀nyí : ( answer the following questions)
- ——- ni o máa ń dọ̀bálẹ̀ kí àgbàlagbà ( obìnrin/ ọkùnrin)
- Ẹ káàsán ni ìkíni fun ——– ( ọ̀sán / alẹ́ / ìrọ̀lẹ́)
- Ta ló máa ń kúnlẹ̀ kí àgbàlagbà? ( ọkùnrin / obìnrin)
- Ẹ kú ìrọ̀lẹ́ ni ìkíni fún ——- ( ọ̀sán / ìrọ̀lẹ́)
- Ìkíni fún alẹ́ ni —— ( ẹ káalẹ́/ ẹ káàsán)
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]
The note is very good and well explanatory