Back to: Yoruba Primary 1
Létà márùn-úndìnlọ́gbọ̀n (25 letters) ló wà nínú álífábẹ́ẹ̀ti ède Yorùbá. Ó já sí wípé a ní fáwẹ̀lì méje (7 vowels) àti kọ́ńsónáǹti méjìdinlògún (18 consonants). Àwọn náà nìwọ̀nyí:

























IṢẸ́ ṢÍṢE
Tọ́ka sí àwòrán tó ṣe àfihàn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí: (match the following names to the right objects)
1. OMO
2. MAALU
3. EJO
4. WAALA