ÀFIWÉ ÌRÓ ÈDÈ GẸ̀Ẹ́SI ÀTI ÌRÓ ÈDÈ YORÚBÁ ( comparing English and Yoruba language sounds)̣

Bi a bá wo ìrísí àwọn ìró èdè Yorúbà àti ti Gẹ̀ẹ́sí kan, wọ́n jọ ara wọn, èyí ni à ń pè ní ìjọra. A tún ṣe àkíỳesí pe áwọn ìró èdè Yorùbá kan kò sí nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì, tàwọn Gẹ̀ẹ́si kan náà kó sí nínú èdé Yorùbá, èyí ni àwọn ìyàtọ́. Ẹ jẹ́ ká wò wọ́n ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.

ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ ÀTI GẸ̀Ẹ̀SÌ

ÌRÓ ÈDÉ YORÚBÁ ÌRÓ ÈDÈ GẸ̀Ẹ́SÌ
A  B   D   E   Ẹ A  B  C  D  E
F  G  GB  H  I F  G  H  I  J
J  K  L  M  N K  L  M  N  O
O  Ọ  P  R  S P Q   R  S  T
Ṣ  T  U  W  Y U  V  W  X  Y  Z

 

ÌJỌRA ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ ÀTI GẸ̀Ẹ́SÌ

ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ ÌRÓ ÈDÈ GẸ̀ÈSÌ
A  B   D   E   F A  B   D  E  F
G  H  I  J  K G  H  I  J  K
L  M  N  O  P L  M  N  O  P
R  S  T  U  W R  S  T  U  W
Y Y

 

ÌYÀTỌ̀ ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ ÀTI GẸ̀Ẹ́SÌ

ÌRÓ ÈDÉ YORÙBÁ ÌRÓ ÈDÈ GẸ̀Ẹ́SÌ
Ẹ    GB    Ọ   Ṣ C    Q    V    X    Z

 

IṢẸ́ ṢÍṢE

Kọ àwọn álifábẹ́ẹ̀tì tí a lè rí nínú èdè Yorùbá ṣùgbọ́n tí a kò lè rín nínú èdè Gẹ̀ẹ́si (write the alphabets that can be found in Yoruba Language but are not in English language)

 

For more class notes, homework help, exam practice, download our App HERE

Join ClassNotes.ng Telegram Community for exclusive content and support HERE

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!