Back to: Yoruba Primary 1
Ọmọlúàbí ni ọmọ tí ó bá ní ìtẹríba tó sì ń fi ọ̀wọ̀ fún àwọn àgbàlagbà. Ìbọ̀wọ̀fágbà ṣe pàtàkì, ó si ṣe kókó. Bi àgbàlagbà b́a gbé ẹrú dáni, ọmọdé náà yóò bá a gbé e. Bí ìjà bá bẹ́ sílẹ̀ láàrin ọmọdé méjì, bí àgbà bát ti bá wọn sọ̀rọ̀, ìjà náà ní lati párí ni. A ní láti bọ̀wọ̀ fún àwọn àgbà kí àwa náà lè ri ẹni bọ̀wọ̀ fún wa bó dọ̀là.
Àpẹẹré:
- Ọmọlúabí ní ìtẹríba
- Ọmọlúabí á ma dìde fún bàbá àgbà láti jókòó nitorí ó ní ìtẹríba.
- Ọmọlúabí a ́ ma fọ abo
- Ọmọlúabí á ma tọ́jú ilé.
- Ọmọlúabí á ma dáná oúnje.
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]