Back to: Yoruba Primary 1
Orin ìrẹmọlẹ́kún ni àwọn orin tị́ a maá ń kọ láti fa ọjú ọmọ ọwọ́ tó ń sunkún mọ́ra kí ó lè ba à dákẹ́ ẹkún tó ń sun. Ìyá ọmọ tàbí ẹnikẹ́ni tó bá gbé ọmọ yìí lọ̀wọ́ nígbà tí ó ń sunkún ló máa ń kọ orin ìrẹmọlẹ́kún.
Díẹ̀̀ lára àwọn orin ìrẹmọlẹkún náà nìwọ̀nyí:
- Taní ba mi lọmọ wí o?
Adedekún dekún o
Ìyá rẹ̀ ló ba wí o
Adedekún dekún o.
- Ta ló nà án o?
Ẹyẹ ni o
Sọ̀kò bá o
Kó sálọ
- Ìjó ọmọ́ mò n jó
Ìjó ọmọ mò n jó o
Kò síjó ẹ
Ko síjò ẹlẹ́yà lẹ́sẹ̀ mi
Ìjó ọmo ̣mò n jo ó
IṢẸ́ ṢÍṢE
Kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kọ orin ìrẹmolẹ́kún fún olùkọ́ wọn (sing a lullaby for your teacher).
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]