Back to: Yoruba Primary 1
- Já itànná to ń tàn
Tó tutù tó si dára
Má dúró dọjọ̣́ ọ̀la.
Àkókó ṣuré tete.
- Iyán loúnjẹ
Ọkà loògùn
Àirí rárá là ń jẹ̀kọ
Kẹ́nu má dilẹ́ nit i gúgúrú
- Adìyẹ mi, èyi tí mo rà
Mo tọ́jú rẹ̀, ó si dàgbá
Lọ́sàn ọjọ́ kan
Ẹ̀mi kò mọ́ pé ó ti jẹun lọ
Ó bọ́ sí kòtò, òjò si pá
Bàbá bá mi gbé
Gbígbé tí mo gbe
Gbígbọ̀n ló ń gbọ̀n
Láì fara pa
Ó yẹ́yin mẹ̣́wàá
Ó pa mẹ́sàn- an
Ó fì̀kan delé
Bọ́mọdé ò kú
Àgbà ní dà.
IṢẸ́ ṢÍṢE
Kí àwọn akẹ́kọ̀o ka àròfọ̀ lóri àwọn nǹkan tó wà ní àwọn àyiká wọn.
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]