PÍPE ÌRÓ ÈDÈ: ÌRÒ FÁWẸ̀LÌ ARÁNMÙPÈ (pronouncing nasalized vowel sounds)

Ìró fáwẹ̀lì aránmúpè márùn-ún mi a ní nínú èdè Yorùbá, bí a bá fi ojú àmì ohùn òkè (mí) mò wọ́n. Bi a bá tún wò wọ́n ni ibámu pẹ̀lú àmi ohùn àárin (re) àti àmi ohùn ìsàlẹ̀ (dò), a ó tún ní marùn-ún-márùn-ún mìíràn. Lápapọ̀, a ó ní ìró fáwẹ̀lì aránmúpè mẹ́ẹ̀ẹ́dógún. Àwọn nàá nìwọ̀nyí.

Ohùn ìsàlẹ̀ (low tone) Oh̀un Ààrin (mid- tone) Ohùn òkè (high- tone)
àn an án
èn en én
ìn in Ín
ọ̀n ọn Ọ́n
ùn un Ún

 

Iṣẹ́ síṣe

Ka áwọn ìró fáwẹ̀lì aránmúpè wọ̀nyí jáde:

Ohùn ìsàlẹ̀ (low tone) Oh̀un Ààrin (mid- tone) Ohùn òkè (high- tone)
àn an án
èn en én
ìn in ín
ọ̀n ọn ọ́n
ùn un ún
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!