ỌJỌ́ TÓ WÀ NÍNÚ Ọ̀SẸ̀ ( Days of the week)

Kí ìmọ́ mọ̀ọ́kọ- mọ̀ọ́kà tó dé ní àwọn Yorùbá ti ní orúkọ tí wọ́n ń pe ọjọ́ kọ̀ọ́kan tó wà nínú ọ̀sẹ̀. Àmọ́ nigbà tí imọ̀ mọ̀ọ́kọ- mọ̀ọ́kà dé, a bẹ̀rẹ̀ sí ní pe àwọn ọjọ́ wọ̀nýi bí àwọn òyìnbó Gẹ̀ẹ́sì ṣe ń pè wọ́n.

GẸ̀Ẹ́SÌ YORÙBÁ
Sunday Àìkú
Monday Ajé
Tuesday Ìṣẹ́gun
Wedneaday Ọjọ́rú
Thursday Ọjọ́bọ̀
Friday Ẹtì
Saturday Àbámẹ́ta

 

Iṣẹ́ ṣịṣe

Kọ orin ọjọ́ ọ̀sẹ̀

 

error: Content is protected !!!