Back to: Yoruba Primary 1
Orin: Ìmọ́tótó ló le ṣẹgun àrùn gbogbo
Ìmọ́tótó ló le ṣẹ̀gun àarùn gbogbo
Ìmọ́tótó ilé
Ìmọ́tótó ara
Ìmọ́tótó oúnjẹ
Ìmọ́tótó ló le ṣẹ́gun àrùn gbogbo
Check pictures in pry 2
IṢẸ́ ṢÍṢE
- Ǹjẹ́ eyin fífò ṣe pàtàki? (Bẹ́ẹ̀ni / bẹ́ẹ̀kọ́)
- Àwọn wo ló ń gẹ irun? ( obìnrin / ọkùnrin)
- Àwọn —— ló ń di irun ( ọkùnrin / obìnrin)
- Ṣé ó yẹ ki á máa gé èékánná wa? ( Bẹ́ẹ̀kọ́ / bẹ́ẹ̀ni)
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]