Back to: Yoruba Primary 1
Ipa tí orin ń kó nínú ìgbésí ayé ọmọ ènìyàn kò ṣe é fi ọwọ rọ́ sẹ́yìn. Àkíyèsi fi hàn pé àwọn ẹ̀kọ́ tí a bá kọ́ nípasẹ̀ orin máa ń tètè wọnú ọpọlọ àti pé kì í nira láti rántí wọn. Bóyá éyi ni àẉon Yorùbá rò tí wọ́n fi máa ń lo orin láti kọ́ àwọn ọmọ wọn ní ìwà tó yẹ kí wọ́n máa wù láàrin àwùjọ.
Díẹ̀ lára àwọn orin náà nìwọ̀nyì:
- Ọmọ tó mọ̀ya rẹ lóju o
O tí ṣetàn láti parun
Ìyà tò jìyà pọ̀ tori rẹ̀
Ọmọ tó mọ̀ya rẹ lòjú o
O tí ṣetàn láti parun
- Ṣemí lọ́mọ réré
Tó gbọ́ tòbi rẹ́
Ọ́mọ́ tó gbọràn
Ọmọ ti kìí bá òbí rẹ̀ jiyàn
Ní ko ṣe mí ò Olúwa.
IṢẸ́ ṢÍṢE
Kọ orin akọ́mọníwà kan fún olùkọ rẹ (sing a moral song for your teacher)
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]