Back to: Yoruba Primary 1
- Yí ẹsẹ̀ ré sí apá kan
Mạ́ ṣe pa kòkòrò nì
Kòkòrò tí ìwọ kò lè dà
Ọlọ́run ló lè da
- Bí o bá fẹ́ sọdá ní títì
Rọra wo òsì wọ̀tún
Tún wo òsì lẹ́ẹ̀kan si
Kí o wá sáré kọjá.
- Ewúrẹ́ jẹ́ ẹran ilé
Tó máa ń jìyà púpọ̀
Nítorí àìgbọràn rẹ̀
Bí wọ́n bá na ewúrẹ́
Á gbọ́n etí méjéèjì pépé
Á tún padà síbi ti
Ó ti jìyà lẹ́ẹ̀kan
Ẹ̀yin ọmọdé ẹ tẹ́tị́ gbọ́
Ẹ má ṣe bí ewúrẹ́
Ẹran aláìgbọnràn
ISE SISE
Ka àròfọ̀ lóri ewúrẹ́ fún olùkọ́ rẹ. (recite a poem on goat for your teacher)
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]