ORÍṢÌÍRÍṢÌÍ ẸYE ÀTI ẸRAN ODÒ (Birds and water animals)

Ẹyẹlẹ ( pigeon)
Igún ( vulture)
Pẹ́pẹ́yẹ( Duck)
Awó/ Ẹtù (Guinea fowl)
Àdán (bat)
Àṣạ́ (hawk)
Ọ̀kín ( peacock)
Idì (eagle)
Tòlótòló (turkey)

 

ÀWỌN ẸRAN ODÒ (WATER ANIMALS)

Ẹja (fish)
Aláńkàn (crab)
Ọ̀nì (crocodile)
Pẹ́pẹ́yẹ (goose)
Ejò odò ( Anaconda)
Ọ̀pọlọ́ (toad)
Kọ̀ǹkọ̀(frog)

IṢẸ́ ṢÍṢE

DARÚKỌ ÀWỌN ẸRAN ODÒ ATI ẸYE MARÙN- ÚN- MÁRÙN –ÚN

ẸRAN ODÒ ẸYẸ
   
   
   
   
   

 

Get more class notes, videos, homework help, exam practice etc on our app [CLICK HERE]

Upgrade your teaching with ready-made & downloadable class notes on our app [CLICK HERE]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!