ÀKÓKÒ LÁÀRIN ỌJỌ́ ( greetings during the day)

Gbọgbo àsìkò tó wà ńinú ọ̣dún ni ìkínI wà fún ni àwujọ Yorùba. Ọ̀kan pàtàki lára àwọn ọ̀na tí à ń gbà láti mọ ọmọlúàbi ni ikíni jẹ́. Ni ilẹ̀ Yorùba, ọkùnrin a máa dọ̀bál̀ẹ̣̀ nígbá tí obìnrin á fi orúnkún rẹ̀ méjéèjì kúnlẹ̀ láti kí àgbàlagbà.

Ẹ káàáro bàbá (goodmorning daddy)
Ẹ káàáro màmá (goodmorning mummy)
Ẹ káàsan màmá (good afternoon mummy)
Ẹ kú ìrọ̀lẹ́ màmà (good evening mother)
Ẹ káalẹ Bàbá mi (good evening father
Ó dàárọ̀ bàbá àti ìyá ni goodnight my father and my mother)

Ọ̀rọ̀ tó yẹ láti mọ̀

Ààro   – morning

Ìrọ̀lẹ́   – evening

Ọ̀sán   – afternoon

Kúnlẹ̀ –         kneel down

Ọkùnrin        –  male

Obìnrin         – female

Dọ̀bálẹ̀ – postrate

Àgbàlagbà – elder

 

IṢẸ́ ṢÍṢE

Dáhùn ìbéèrè wọ̀nyí : ( answer the following questions)

  1. ——- ni o máa ń dọ̀bálẹ̀ kí àgbàlagbà ( obìnrin/ ọkùnrin)
  2. Ẹ káàsán ni ìkíni fun ——– ( ọ̀sán / alẹ́ / ìrọ̀lẹ́)
  3. Ta ló máa ń kúnlẹ̀ kí àgbàlagbà? ( ọkùnrin / obìnrin)
  4. Ẹ kú ìrọ̀lẹ́ ni ìkíni fún ——- ( ọ̀sán / ìrọ̀lẹ́)
  5. Ìkíni fún alẹ́ ni —— ( ẹ káalẹ́/ ẹ káàsán)

 

For more class notes, homework help, exam practice, download our App HERE

Join ClassNotes.ng Telegram Community for exclusive content and support HERE

1 thought on “  ÀKÓKÒ LÁÀRIN ỌJỌ́ ( greetings during the day)”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!