ORUKO AWON NNKAN TO WA NI AYIKA (Names of things in our environment)

Garawa- pail
Ife-cup
Adíẹ- chicken
Ṣíbí- spoon
Adé- crown
Íkòkò- pot
Ewúrẹ́- goat
Àga- chair
Ajá- dog
Aṣọ- cloth
kọ́kọ́rọ́- key
Òòyà- comb
ọṣẹ- soap
fáànù-fan
Ẹ̀rọ- amọ́mitutù (refridgerator)
Apẹ̀rẹ̀(basket)
Igì (tree)
Ibùsùn (bed)
Ìkọ́lẹ̀(dust pan)
Ẹ̀rọ Amóhùnmáwòrán (television)
Abọ́ (plate)
Àtùpà (lantern)

IṢẸ́ ṢÍṢE

Yà àwòrán tọ́ ṣe àfihàn orúkọ àwọn nǹkan wọ̀nyi: (́́draw the right objects)

Aga

Ife

Aja

Garawa

Adie

For more class notes, homework help, exam practice, download our App HERE

Join ClassNotes.ng Telegram Community for exclusive content and support HERE

1 thought on “ORUKO AWON NNKAN TO WA NI AYIKA (Names of things in our environment)”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!