Back to: Yoruba Primary 1
Oríṣìíriṣìí ni orin tí awọn Yorùba màa ǹ kọ bí wọ́n bá ń ṣe eré ìdárayá. Díẹ̀ lára áwọn orin náà nìwọ̀nyí:
Lile: Ẹyẹ mẹ́ta tolongo wáyé
Ègbè: tolongo
Líĺé: Ọ̀kan dúdú aró
Ègbe: Tolongo
Lílé: Ọ̀kan rẹ̀rẹ̀ osùn
Ègbè: Tolongo
Lílé: Ṣó ṣò sọ́ firùbalẹ̀
Ègbè: Ṣóò
Ẹkùn mẹ́ran
Lílé: Ẹkùn mẹ́ran
Ègbè: mẹ́ẹ̀
Lílé: Ó torí bọgbó
Ègbè: Mẹ́ẹ̀
Lílé: Ó tọrùn bọgbà
Ègbè: mẹ́ẹ̀
Lílé: Ó fẹ́ mu
Ègbè: Mẹ́ẹ̀
Lílé: Kò mà lé mu
Ègbè: Mẹ́ẹ̀
Lílé: Ojú ẹkùn ń pọ́n
Ègbè: Ìrù ẹkùn ń le
IṢẸ́ ṢÍṢE
Kí àwón akẹ́kọ̀ọ́ kọ orin eré ìdárayá kan fún olùkọ́ ( SING A GAME SONG FOR YOUR TEACHER)
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session nowGet more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]