PÍPE ÌRÓ ÈDÈ: ÌRÒ F́AWẸ̀LÌ ÀÌRÁNMÚPÈ (pronouncing oral vowel sounds

Ìró fáwẹ̀lì àìránmúpè méje ni a ní ninú èdè Yorùbá, bí á ba fi ojú àmi ohùn òkè (mí) mò wọ́n. Bí a bá tún wò wọ́n ní ìbámu pẹ̀lu àmi ohùn ààrin (re) àti àmí ohùn ìsàlẹ́ (do), a ó tún ní méje- méje mìíràn.

Lápopọ̀ a ó ni ìró fáwẹ̀lì àìrànmúpe mọ́kànlélógún. Àwọn náà nìwọ́nyí.

Ohùn  ìsàlẹ̀ (low- tone)Ohùn Ààrin (mid- tone)Ohùn òkè (high-tone)
a
e
Ẹ̀ẹ́
i
o
ọ̀ọ́
uuu

 

 

IṢẸ́ ṢÍṢE

Pe àwọn ìrò fáwẹ̀lì àìránmúpè wọ̀nyí jáde lẹ́nu kí o sì tún wọn kọ sílẹ̀: ( pronounce the following oral vowel sound and re-write them)

Ohùn  ìsàlẹ̀ (low- tone)Ohùn Ààrin (mid- tone)Ohùn òkè (high-tone)
a
   
e
   
ẹ̀Ẹ́
   
i
   
o
   
ọ̀Ọ́
   
uuU
   

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *