PÍPE ÌRÓ ÈDÈ: ÌRÒ FÁWẸ̀LÌ ARÁNMÙPÈ (pronouncing nasalized vowel sounds)

Ìró fáwẹ̀lì aránmúpè márùn-ún mi a ní nínú èdè Yorùbá, bí a bá fi ojú àmì ohùn òkè (mí) mò wọ́n. Bi a bá tún wò wọ́n ni ibámu pẹ̀lú àmi ohùn àárin (re) àti àmi ohùn ìsàlẹ̀ (dò), a ó tún ní marùn-ún-márùn-ún mìíràn. Lápapọ̀, a ó ní ìró fáwẹ̀lì aránmúpè mẹ́ẹ̀ẹ́dógún. Àwọn nàá nìwọ̀nyí.

Ohùn ìsàlẹ̀ (low tone)Oh̀un Ààrin (mid- tone)Ohùn òkè (high- tone)
ànanán
ènenén
ìninÍn
ọ̀nọnỌ́n
ùnunÚn

 

Iṣẹ́ síṣe

Ka áwọn ìró fáwẹ̀lì aránmúpè wọ̀nyí jáde:

Ohùn ìsàlẹ̀ (low tone)Oh̀un Ààrin (mid- tone)Ohùn òkè (high- tone)
ànanán
ènenén
ìninín
ọ̀nọnọ́n
ùnunún

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *