PÍPE ÌRÓ ÈDÈ- ÌRÓ KỌ́ŃSÓNÁǸTÌ ( Pronouncing consonant sounds)

PÍPE ÌRÓ ÈDÈ- ÌRÓ KỌ́ŃSÓNÁNTÌ

(PRONOUNCING CONSONANT SOUNDS)

Ìró kọ́ńsónáǹtì ni àwọn ìrò tí a pè nígbà tí ìdíwọ̀ bá wà fún èémi tó ń ti inú ẹ̀dọ́fóró bọ̀. Méjìdínlógún ni àwọn iró kọ́nsọ́nạ́ntì tó wà nínú èdè Yorùbá. Àwọn náa ni:

Lẹ́tà Ńlá: capital letters)

B D F G GB H
J K L M N P
R S T W Y

 

Lẹ́tà kékeré(small letters)

b d F g gb H
j k l m n p
r s t w y

 

IṢẸ́ ṢÍṢE

Pe àwọn  ìró kọ́ńsónáǹtì wọ̀nyí jáde lẹ́nu kí o si tún wọn kọ sílẹ̀;

b d f g gb h
           
j k l m n p
           
r s s t w y
           

 

 

School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session now

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!