Back to: Yoruba Primary 1
11 Oókànlá |
12 Eéjìlá |
13 Ẹẹ́talá |
14 Ẹẹ́rìnlá
|
15 Aárùn-úndínlógún |
16 Ẹẹ́rìndínlógún |
17 Eẹ̣́tàndínlógún |
18 Eèjìdínlógún |
19 Oókandínlógún |
20 Ogún. |
IṢẸ́ ṢỊṢE
Tọ́ka sí orúkọ tó ń ṣe àfihàn figọ̀ wọ̀nyí: match the figures with the right names)
18 Eéjìlá
16 Ogún
12 Ẹẹtadínlógún
17 Ẹẹ́rindínlógún
20 Eéjìdínlógún
School Owner? Looking for ready-made content and tools to save time and grow easily? Book a free demo session nowGet more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]
Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]