Back to: Yoruba Primary 1
Bi a bá wo ìrísí àwọn ìró èdè Yorúbà àti ti Gẹ̀ẹ́sí kan, wọ́n jọ ara wọn, èyí ni à ń pè ní ìjọra. A tún ṣe àkíỳesí pe áwọn ìró èdè Yorùbá kan kò sí nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì, tàwọn Gẹ̀ẹ́si kan náà kó sí nínú èdé Yorùbá, èyí ni àwọn ìyàtọ́. Ẹ jẹ́ ká wò wọ́n ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.
ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ ÀTI GẸ̀Ẹ̀SÌ
| ÌRÓ ÈDÉ YORÚBÁ | ÌRÓ ÈDÈ GẸ̀Ẹ́SÌ |
| A B D E Ẹ | A B C D E |
| F G GB H I | F G H I J |
| J K L M N | K L M N O |
| O Ọ P R S | P Q R S T |
| Ṣ T U W Y | U V W X Y Z |
ÌJỌRA ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ ÀTI GẸ̀Ẹ́SÌ
| ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ | ÌRÓ ÈDÈ GẸ̀ÈSÌ |
| A B D E F | A B D E F |
| G H I J K | G H I J K |
| L M N O P | L M N O P |
| R S T U W | R S T U W |
| Y | Y |
ÌYÀTỌ̀ ÌRÓ ÈDÈ YORÙBÁ ÀTI GẸ̀Ẹ́SÌ
| ÌRÓ ÈDÉ YORÙBÁ | ÌRÓ ÈDÈ GẸ̀Ẹ́SÌ |
| Ẹ GB Ọ Ṣ | C Q V X Z |
IṢẸ́ ṢÍṢE
Kọ àwọn álifábẹ́ẹ̀tì tí a lè rí nínú èdè Yorùbá ṣùgbọ́n tí a kò lè rín nínú èdè Gẹ̀ẹ́si (write the alphabets that can be found in Yoruba Language but are not in English language)