AGOGO (time)

AGOGO

Àgògo Baba mi

Làra ògiri ló dúró

Pẹ̀lú ọwọ́ méjì rẹ̀

Ọ̀kàn ka wakati

Èkejì ka iṣẹju

Ile- ìwé alágogo

Gbáún!

Gbáún!

Gbáún!

Gbáún!

 

Ilé- ìwé alágogo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *