ÀRỌ̀FỌ̀ KÉÉKÈÈEKÉ LÓRÍ ÀYÍKÁ AKẸ́KỌ̀Ọ́ 2 (poems on pupils’ environment 2)

  1. Yí ẹsẹ̀ ré sí apá kan

Mạ́ ṣe pa kòkòrò nì

Kòkòrò tí ìwọ kò lè dà

Ọlọ́run ló lè da

  1. Bí o bá fẹ́ sọdá ní títì

Rọra wo òsì wọ̀tún

Tún wo òsì lẹ́ẹ̀kan si

Kí o wá  sáré kọjá.

  1. Ewúrẹ́ jẹ́ ẹran ilé

Tó máa ń jìyà púpọ̀

Nítorí àìgbọràn rẹ̀

Bí wọ́n bá na ewúrẹ́

Á gbọ́n etí méjéèjì pépé

Á tún padà síbi ti

Ó ti jìyà lẹ́ẹ̀kan

Ẹ̀yin ọmọdé ẹ tẹ́tị́ gbọ́

Ẹ má ṣe bí ewúrẹ́

Ẹran aláìgbọnràn

 

 

ISE SISE

Ka àròfọ̀ lóri ewúrẹ́ fún olùkọ́ rẹ. (recite a poem on goat for your teacher)

 

Ready to make school management and growth easy? Book your free onboarding session now

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on Android [DOWNLOAD]

Get more class notes, videos, homework help, exam practice on iPhone [DOWNLOAD]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Don`t copy text!