Back to: Yoruba Primary 1
Kí ìmọ́ mọ̀ọ́kọ- mọ̀ọ́kà tó dé ní àwọn Yorùbá ti ní orúkọ tí wọ́n ń pe ọjọ́ kọ̀ọ́kan tó wà nínú ọ̀sẹ̀. Àmọ́ nigbà tí imọ̀ mọ̀ọ́kọ- mọ̀ọ́kà dé, a bẹ̀rẹ̀ sí ní pe àwọn ọjọ́ wọ̀nýi bí àwọn òyìnbó Gẹ̀ẹ́sì ṣe ń pè wọ́n.
| GẸ̀Ẹ́SÌ | YORÙBÁ |
| Sunday | Àìkú |
| Monday | Ajé |
| Tuesday | Ìṣẹ́gun |
| Wedneaday | Ọjọ́rú |
| Thursday | Ọjọ́bọ̀ |
| Friday | Ẹtì |
| Saturday | Àbámẹ́ta |
Iṣẹ́ ṣịṣe
Kọ orin ọjọ́ ọ̀sẹ̀
Mo kí àwon tó pakitiyan láti gbé ìmò nípa àwon ojó tó wà nínú ède abinibi wa, èyi tí a mò sí èdè Yorùbá.
But please if possible, can you correct the spelling for Wednesday for completeness.
Thank you