Back to: Yoruba Primary 1
11 Oókànlá | 12 Eéjìlá | 13 Ẹẹ́talá |
14 Ẹẹ́rìnlá
| 15 Aárùn-úndínlógún | 16 Ẹẹ́rìndínlógún |
17 Eẹ̣́tàndínlógún |
18 Eèjìdínlógún |
19 Oókandínlógún |
20 Ogún. |
IṢẸ́ ṢỊṢE
Tọ́ka sí orúkọ tó ń ṣe àfihàn figọ̀ wọ̀nyí: match the figures with the right names)
18 Eéjìlá
16 Ogún
12 Ẹẹtadínlógún
17 Ẹẹ́rindínlógún
20 Eéjìdínlógún