Back to: Yoruba Primary 1
1 Oókan | 2 Eéji | 3 Ẹẹ́ta |
4 Ẹẹ́rin | 5 Aárùn -ún | 6 Ẹẹ́fà
|
7 Eéje | 8 Ẹẹ́jọ | 9 Ẹẹ́sàn- án |
10 Ẹẹ́wàá |
IṢẸ́ ṢÍŚE
Tọ́ka sí orúkọ tó ń ṣe àfihàn fígọ̀ wọ̀nyi:(match the names with the right figures
5 Eéje
10 Eéji
7 Ẹẹ́ta
2 Aárùn -ún
3 Ẹẹ́wàá