ORIṢÌÍRIṢÌÍ ẸRANKO ILÉ ( Domestic Animals)

Ewúrẹ́( goat)
Àgùntàn ( sheep)
Ẹlẹ́dẹ̀ (pig)
Ajá ( dog)
Ẹsịn (horse)
Ìjàpá ( tortoise)
Olóńgbò ( cat)
Èkúté (rat)
Àgbò (ram
Màlúu ( cow)
Ràkúnmí (camel)
Ehoro(rabbit
Ìgbín (snail)

IṢẸ́ ṢÍṢE

Fi orúkọ sì àwòrán àwón ẹranko ilé wọ̀nyí. (write the names of the following domestic animals)

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

error: Content is protected !!!