Back to: Yoruba Primary 1
Ìró fáwẹ̀lì aránmúpè márùn-ún mi a ní nínú èdè Yorùbá, bí a bá fi ojú àmì ohùn òkè (mí) mò wọ́n. Bi a bá tún wò wọ́n ni ibámu pẹ̀lú àmi ohùn àárin (re) àti àmi ohùn ìsàlẹ̀ (dò), a ó tún ní marùn-ún-márùn-ún mìíràn. Lápapọ̀, a ó ní ìró fáwẹ̀lì aránmúpè mẹ́ẹ̀ẹ́dógún. Àwọn nàá nìwọ̀nyí.
| Ohùn ìsàlẹ̀ (low tone) | Oh̀un Ààrin (mid- tone) | Ohùn òkè (high- tone) |
| àn | an | án |
| èn | en | én |
| ìn | in | Ín |
| ọ̀n | ọn | Ọ́n |
| ùn | un | Ún |
Iṣẹ́ síṣe
Ka áwọn ìró fáwẹ̀lì aránmúpè wọ̀nyí jáde:
| Ohùn ìsàlẹ̀ (low tone) | Oh̀un Ààrin (mid- tone) | Ohùn òkè (high- tone) |
| àn | an | án |
| èn | en | én |
| ìn | in | ín |
| ọ̀n | ọn | ọ́n |
| ùn | un | ún |