Back to: Yoruba Primary 1
PÍPE ÌRÓ ÈDÈ- ÌRÓ KỌ́ŃSÓNÁNTÌ
(PRONOUNCING CONSONANT SOUNDS)
Ìró kọ́ńsónáǹtì ni àwọn ìrò tí a pè nígbà tí ìdíwọ̀ bá wà fún èémi tó ń ti inú ẹ̀dọ́fóró bọ̀. Méjìdínlógún ni àwọn iró kọ́nsọ́nạ́ntì tó wà nínú èdè Yorùbá. Àwọn náa ni:
Lẹ́tà Ńlá: capital letters)
| B | D | F | G | GB | H |
| J | K | L | M | N | P |
| R | S | Ṣ | T | W | Y |
Lẹ́tà kékeré(small letters)
| b | d | F | g | gb | H |
| j | k | l | m | n | p |
| r | s | ṣ | t | w | y |
IṢẸ́ ṢÍṢE
Pe àwọn ìró kọ́ńsónáǹtì wọ̀nyí jáde lẹ́nu kí o si tún wọn kọ sílẹ̀;
| b | d | f | g | gb | h |
| j | k | l | m | n | p |
| r | s | s | t | w | y |