Back to: Yoruba Primary 1
Ìró fáwẹ̀lì àìránmúpè méje ni a ní ninú èdè Yorùbá, bí á ba fi ojú àmi ohùn òkè (mí) mò wọ́n. Bí a bá tún wò wọ́n ní ìbámu pẹ̀lu àmi ohùn ààrin (re) àti àmí ohùn ìsàlẹ́ (do), a ó tún ní méje- méje mìíràn.
Lápopọ̀ a ó ni ìró fáwẹ̀lì àìrànmúpe mọ́kànlélógún. Àwọn náà nìwọ́nyí.
| Ohùn ìsàlẹ̀ (low- tone) | Ohùn Ààrin (mid- tone) | Ohùn òkè (high-tone) |
| à | a | á |
| È | e | é |
| Ẹ̀ | ẹ | ẹ́ |
| ì | i | Í |
| ò | o | ó |
| ọ̀ | ọ | ọ́ |
| u | u | u |
IṢẸ́ ṢÍṢE
Pe àwọn ìrò fáwẹ̀lì àìránmúpè wọ̀nyí jáde lẹ́nu kí o sì tún wọn kọ sílẹ̀: ( pronounce the following oral vowel sound and re-write them)
| Ohùn ìsàlẹ̀ (low- tone) | Ohùn Ààrin (mid- tone) | Ohùn òkè (high-tone) |
| à | a | Á |
| è | e | É |
| ẹ̀ | ẹ | Ẹ́ |
| ì | i | Í |
| ò | o | Ó |
| ọ̀ | ọ | Ọ́ |
| u | u | U |