ÀKÓKÒ LÁÀRIN ỌDÚN ( Season greetings)

Oríṣìíriṣìí ìgbà tó wà nínú ọdún ní ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí dálé, bí a ṣe ń ki ara wa ní àwọn ìgbà wọ̀nyí ló ṣe pàtàki sí wa

Ẹ kú ooru (greetings for the hot/ dry season)

Ìdáhùn ( response): A dupe ( thanks)

Ẹ kú ọ̀gbẹlẹ̀ ( greetings for hot/ dry season)

Ìdáhùn (response): A dupe (thanks)

Ẹ kú òtútù ( greetings for raining season)

Ìdáhùn (response): A dupe ( thanks)

Ẹ kú òjò ( greetings for raining season)

Ìdáhùn (response) : A dupe (thanks)

Ẹ kú ọ̀gìnnìtìn ni ìkíni fún ìgbà tí òjò ń rọ̀ léraléra ( greetings for raining season)

Ẹ kú ọyẹ́ ni ìkíni fún ìgbà ọyẹ́.

(greetings for harmattan period)

 

IṢẸ́ ṢÍṢE

Bawoni a ṣe kíni ni àkókò wọ̀nyii

  1. Ẹ kú ọ̀gbẹlẹ̀ ——————————————-
  2. Ẹ kú òjò ———————————————
  3. Ẹ kú ooru ———————————————

Ẹ kú ọ̀gbẹlẹ̀ ——————————–

1 thought on “ ÀKÓKÒ LÁÀRIN ỌDÚN ( Season greetings)”

Leave a Reply to Pamela Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *