ỌJỌ́ TÓ WÀ NÍNÚ Ọ̀SẸ̀ ( Days of the week)

Kí ìmọ́ mọ̀ọ́kọ- mọ̀ọ́kà tó dé ní àwọn Yorùbá ti ní orúkọ tí wọ́n ń pe ọjọ́ kọ̀ọ́kan tó wà nínú ọ̀sẹ̀. Àmọ́ nigbà tí imọ̀ mọ̀ọ́kọ- mọ̀ọ́kà dé, a bẹ̀rẹ̀ sí ní pe àwọn ọjọ́ wọ̀nýi bí àwọn òyìnbó Gẹ̀ẹ́sì ṣe ń pè wọ́n.

GẸ̀Ẹ́SÌYORÙBÁ
SundayÀìkú
MondayAjé
TuesdayÌṣẹ́gun
WedneadayỌjọ́rú
ThursdayỌjọ́bọ̀
FridayẸtì
SaturdayÀbámẹ́ta

 

Iṣẹ́ ṣịṣe

Kọ orin ọjọ́ ọ̀sẹ̀

 

1 thought on “ỌJỌ́ TÓ WÀ NÍNÚ Ọ̀SẸ̀ ( Days of the week)”

  1. Mo kí àwon tó pakitiyan láti gbé ìmò nípa àwon ojó tó wà nínú ède abinibi wa, èyi tí a mò sí èdè Yorùbá.

    But please if possible, can you correct the spelling for Wednesday for completeness.

    Thank you

Leave a Reply to Tunde Aikomo Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *